Àjọ INEC Sún Ọjọ́ Ìdìbò Gómìnà, Ilé Aṣòfin Sí Iwájú
Àjọ Nigeria’s Independent National Electoral Commission (INEC) ti sún ọjọ́ Ìdìbò Gómìnà, Ile Aṣòfin ti ìpínlẹ̀ tí ó yẹ kí ó wáyé ní ọjọ́ kọkànlá oṣù yìí sí iwaju.
Nínú àkọsílẹ̀ ní alẹ́ ọjọ́ Ọjọ́rú láti òpó ẹ̀rọ ayélujára Twitter,…