Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Mauritania Ṣẹ́ Àhesọ Ọ̀rọ̀ Pé Àwọn Pe Àwọn Ajaguntà Láti Orílẹ̀-èdè Russia Láti Wá Ràn Wọ́n Lọ́wọ

0 192

 

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Mauritania, Mohamed Ghazouani ti sọ wí pé ìjọba òun kò ní lọkàn rárá láti lọ pe àwọn Ajaguntà ti ìkọ Russia’s Wagner láti Orílẹ̀-èdè Russia láti wá báwon kọjú àwọn alákatakítí ẹ̀ṣìn Ìsìláàmù.

Ìròyìn ró pé àwọn orílẹ̀-èdè ní agbègbè
Sahel pẹlu Orílẹ̀-èdè Mali – alamúlétì Orílẹ̀-èdè Mauritania, pé wọ́n ń lo jagunjagun láti ọ̀dọ̀ ọmọ ogun Aládáni láti kojú ikọ̀ ti Jihadi tó ti fa ikú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn.

“Kó rí bẹ́ẹ̀, Orílẹ̀-èdè alágbára tó se mú yangàn ni wá, a o sì máa rí bẹ́ẹ̀ títí láyé” .
Ọgbẹni Ghazouani sọ bẹ.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button