Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bu Ọwọ́ Lu Ìlànà Tuntun Lórí Ìmúgbóòrò Iṣẹ́ Àgbẹ̀

Mínísítà fún iṣẹ́ àgbẹ àti ìdàgbàsókè Ìgbèríko, Mohammed Abubakar, sọ pé ìjọba àpapọ̀ ti bu ọwọ́ lu ìlànà tuntun lórí ètò ìmúgbóòrò iṣẹ́ àgbẹ̀ láti ri pé iṣẹ́ àgbẹ̀ tẹ̀síwájú ní ẹ̀ka ìmọ̀ ẹ̀rọ, kí oúnjẹ leè pọ̀ tabua ní orílẹ̀-èdè…

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Orilẹ̀-ède Nàìjíríà Fi Àbádòfin Peace Corps Sọwọ́ Sí Ààrẹ Fún Ìbuwọ́lù

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Orile-ede Nàìjíríà ti fi àbádòfin Peace Corps sọwọ́ sí Ààrẹ fún bíbu ọwọ́ lù. Eléyìí wáyé ní ọjọ́ ọjọ́ru ọ̀sẹ̀ yìí, ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin , ọdún 2023, nípasẹ̀ lẹ́tà tí wọ́n kọ sí ààrẹ. Mẹ́ta òkodoro ẹ̀dà…
button