Ẹgbẹ́ Kan Ní Gúsù-Ìlà Oòrùn Gba Ààrẹ Asẹ̀sẹ̀dìbòyàn Ní Ìmọ̀ràn Ìjọba Àjùmọ̀ṣe
Ẹgbẹ́ Southeast Destiny Movement for Bola Tinubu, SDMBAT, ti gba ààrẹ asẹ̀sẹ̀dìbòyàn ní ìmọ̀ràn láti jẹ́ kí ìjọba rẹ̀ ṣe iṣẹ́ takuntakun lórí ìṣọ̀kan, ọrọ̀ ajé, ààbò, ìwà ìbàjẹ́ tó ń ba orílẹ̀-èdè yìí fíra, kí ìjọba rẹ̀ sì jẹ́ ti…