Òruru Orílẹ̀-èdè Mexico Ní Àkókò Yìí Àrà Ọ̀tọ̀ Ni
Àwọn aláṣẹ orílẹ̀-èdè Mexico ti rọ àwọn ènìyàn káàkiri orílẹ̀-èdè náà láti ri pé wọ́n dáàbòbó ara wọn látàrí iruru tó gbóná janjan to gbòde kan.
Elétò ìlera sọ pé ènìyàn mẹ́fà ti jẹ́ Ọlọ́run ní ìpè látàrí èyí títí di…