Ẹgbẹ̀rún Márùn Ó Lé Díẹ Ọmọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìpínlẹ̀ Kogi
Ó lé ní Ẹgbẹ̀rún márùn Ọmọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC tí wọn lọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ oṣèlú alátakò PDP ní Ìpínlè Kogi báyìí.
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní ọjó Àìkú ní Avrugo àti wọ́ọ̀dù tó múlé tìwọn, ní agbègbè ìbílẹ̀ ìjọba Igalamela/Odolu ti ìpínlẹ…