Ikọ̀ Super Falcons kúrò Ní Amẹ́ríkà,Dojúkọ Japan Fun Ìdíje Ọlọ́rẹ̀ẹ́sọ̀rẹ́
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Super Falcons ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ọ̀ga ọ̀ta Adúláwọ̀ nígbà mẹ́sàn án àti akópa nígbà gbogbo ìdíje eré bọ́ọ̀lù FIFA ti àwọn obìnrin ti rin ìrìnàjò kúrò ní orílẹ̀-èdè Àmẹ́ríkà láti…