Take a fresh look at your lifestyle.

Òsìsẹ́ Ọlọ́pàá Ọ̀tẹlẹmúyẹ́ DSS Ti Nàìjíríà Fi Adúnàádúrà Àwọn Ajínigbé Sí Àkàtà Wọn

0 237

 

Àwọn òsìsẹ́ Ọlọ́pàá DSS ti Nàìjíríà ti jẹ́ kó di mímọ̀  pé Adúnàádúrà àwọn ajínigbé Ọkọ̀ Reluwé tó ń lọ sí Kàdúná tí wọ́n fi ènìyàn sínú ìgbèkùn, Ọ̀gbẹ́ni Tukur Mamu sì wà ní àkàtà wọn.

Agbẹnusọ àwọn òsìsẹ́ Ọlọ́pàá Ọ̀tẹlẹmúyẹ́ DSS, Peter Afunuanya lo sọ bẹ́è ní ọjọ́ ọjoru pe ogbeni Mamu ni wọ́n gbámú síkún ní  Kairo ti Egypiti ni ọjọ́ kẹfà osù kẹ́sàn án, 2022 nigbati ó ń lọ si Saudi Arabia.

O fi kun pe, wọn ti dá Ọ̀gbẹ́ni Mamu padà sí orílẹ̀ èdè yìí ni ọjọ́ keje osù kẹ́sàn án, 2020.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button