Ìgbìmọ̀ G7 Bú Ẹnu Àtẹ Lù Bí Russia Ṣé Ji Olórí Zaporizhzhia Gbé
Ẹgbẹ́ ẹlẹni-Méje (G7) àwọn orílẹ̀-èdè tó ní ilé-iṣẹ́ jùlọ tí bú ẹnu àtẹ lù bí orílẹ-èdè Russia ṣé ji olórí ilé-iṣẹ́ àgbàrá ìparun Zaporizhzhia (Zaporizhzhia nuclear power plant) gbé àti pé kí wọ́n jọwọ ìlé-íṣẹ́ náà lẹsẹkẹsẹ fún orílẹ̀-èdè…