Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Kẹdun Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè South Korea Lórí Àjálù Tó Ṣẹlẹ̀ Sí Wọ́n

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí kẹdun ọkàn sí Ààrẹ Yoon Suk-yeo, Ìjọ̀ba àti àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè South Korea, àti sí àwọn ìdílé tí àwọn ọmọ wọ́n pàdánù ẹmi nínú ìṣẹlẹ̀ àjálù tó wáyé ní Itaewon, ni àgbègbè Seoul. Ààrẹ wà fí ádùrá ìwòsàn ní…

Ẹ̀ka Òfurufú Tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Wà Ni Ipò Kejì Tó Dára Jùlọ́ Làgbáyé Lẹyìn Àjàkálẹ̀ Àrùn…

Nàìjíríà wà ní ipò Kejì lẹyìn Columbia nínù Ìgbìmọ̀ apapọ ọkọ òfurufú àgbáyé lori atunto lẹyìn Covid-19. Mínísítà fún Ọkọ Òfurufú, Alàgbà Hadi Sirika fí ìdí rẹ̀ múlẹ̀ nígbàtí o ń bá àwọn aṣòfin àpapọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọrọ ní Ọjọ́rú,…
button