Take a fresh look at your lifestyle.

U-23 AFCON: Nàìjíríà Gbo Ewúro Sí Ojú Tanzania Ní Ayò 2-0

0 171

Ẹgbẹ́ agbabọọlu U-23 Nàìjíríà, Olympic Eagles, ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, bórí Young Taifa Stars tí Tanzania 2-0 ní ifẹsẹwọnsẹ ẹlẹẹkeji U-23 Africa Cup of Nations Qualifier tó wáyé ní pápá iṣere Lekan Salami, Ibadan.

Ifẹsẹwọnsẹ náà gbóná gidigidi ní ìdá àkọ́kọ́, ṣùgbọ́n àwọn àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà múra sí èré náà tí Oguniyi Omojesu sí gbà àmì ayò àkọ́kọ́ wọlé fún ìkọ Nàìjíríà ní ìdá Kejì nígbàtí Success Makanjuola gbà àmì ayò Kejì wọlé níbí ẹni bá láyà, kò wá wọ̀ tí afọn-feèrè fún wọ́n.

Lekan Orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.