Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Gbóríyìn Fún Élétó Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC
Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara àti Olùdásílẹ̀ Ajike People Support Centre, Iyaafin Olufolake Abdulrazaq tí ṣé àbẹwò sí Adewole Ward ní ìjọba ìbílẹ̀ Ìwọ̀-oòrùn tí Ìpínlẹ̀ náà.
Ìyàwó Gómìnà lásìkò àbẹwò rẹ̀ náà gbóríyìn fún àwọn élétó ẹgbẹ́…