Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdíwọ́ Bá Ẹ̀rọ́ Ayélujára Orílẹ̀-èdè Mauritania Lẹyìn Ìffẹ́hónúhàn Àwọn Aráàlú

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Mauritania ní Ọjọ́rú gé ìkànnì ayélujára kúrò lórí àwọn ẹ̀rọ́ alágbèéká (Phones), lẹyìn ìfẹ́hónúhàn àwọn aráàlú lórí ikú ọdọmọkunrin kàn ní atìmọlé ọlọ́pàá. Gbogbo awọn asopọ intanẹẹti lori awọn foonu alagbeka ti lọ…

Bánkì Àgbáyé Buwọ́lù Ètò Ẹyàwó Orílẹ̀-èdè China Látí Ṣé Àtìlẹ́yìn Ìṣẹ́ Ọ̀gbìn Ìrẹ́sì lọpọ̀lọpọ̀

Bánkì Àgbáyé tí fọwọ́sí ẹyàwó tí ọ̀ọ́dúrún dín díẹ̀ mílíọ̀nù dọla ($255m) látí ṣé àtìlẹ́yìn ètò tí yóò ṣé àdínkù eruku, tí yóò sí rán àwọn àgbẹ lọ́wọ́ lórí iṣẹ́ ọ̀gbìn Ìrẹ́sì ní àárín gbùngbùn China. Olùdarí Àgbà kàn ní Bánkì Àgbáyé…

Àkọrín Ọmọ Nàìjíríà Ayra Starr Tí Wọ́gilé Ìrìn-àjò Rẹ̀ Sílẹ Òkèèrè Látàrí Ètò Ìwé Ìrìn-àjò

Ogbontarigi àkọrín Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ayra Starr tó ń kọ́rín káàkiri àgbáyé lọ́wọ́lọ́wọ́ tí wọ́gílé ìrìn-àjò látí lọ́ sí Berlin, Bergenfest, ati Copenhagen lórí òfin ètò ìwé ìrìn-àjò àwọn Orílẹ̀-èdè wọnyí. O ṣé ìkéde yìí lórí…

Àwọn Ọlọ́pàá Mú Àwọn Afurasí Lórí Èrò Látí Dá Ìfilọ́lẹ̀ Ìjọba Túntún Ìpínlẹ̀ Kano Rú

Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Kano tí mú àwọn afurasi mẹrindinlọgọrun-un (96) lórí ẹsùn èrò láti dá ayẹyẹ Gómìnà túntún ní ìpínlẹ̀ náà rú. Kọmisọna Ọlọ́pàá tí ìpínlẹ̀ náà, Usaini Gumel sọ́ èyí dì mímọ ní ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá Command ní Bompai.…

China Ṣetán Látí Ṣé Àtìlẹ́yìn Àlà Àwọn Ọ̀dọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Olùdarí tí Ilé-iṣẹ́ Àṣà Orílẹ̀-èdè China ní Abuja, Ọ̀gbẹ́ni Li Xuda, sọ pé Ìjọba Orílẹ̀-èdè China tí ṣetán láti ṣé àtìlẹ́yìn àwọn àlà àtí ìrètí àwọn ọmọ Áfríkà, pàápàá fún ọjọ́ iwájú àwọn ọ̀dọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Li sọ èyí dì mímọ̀…
button