Ààrẹ Nàìjíríà Pàṣẹ Àbójútó Ààbò Tó Péye Fún Àwọn Élétó Ààbò Orílẹ̀-èdè Yìí
Ààrẹ Bola Tinubu tí pàṣẹ fún àwọn élétó ààbò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti pèsè ààbò tó péye fún àwọn aráàlú ní gbogbo àgbègbè lórílẹ̀-èdè yìí.
Ààrẹ pàṣẹ fún àwọn élétó ààbò ní Ọjọ́rú nígbàtí Ó ṣé ìpàdé pẹ̀lú àwọn alákóso ààbò náà ní…