Gómìnà Kwara Fọwọ́sí Ìwé Ètò Ọkọ̀ Ìrọrùn Fún Àwọn Ọmọ Ilé-ìwé, Àtí Àwọn Òṣìṣẹ́
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara ní àárín gbùngbùn àríwá Nàìjíríà, AbdulRahman AbdulRazaq tí fọwọ́sí gbígbé àwọn ọkọ àkérò ìjọba jáde láti ṣé ìrọrùn fún àwọn ọmọ ilé-ìwé àti àwọn òṣìṣẹ́ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga láàrín Ilorin, Olúìlú àtí àgbègbè rẹ̀.…