Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-iṣẹ́ Ìròyìn Tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bẹ̀rẹ Àtúnyẹwò Iṣẹ́ Ẹká Rẹ̀

Ilé-iṣẹ́ tí Ìròyìn àti àlàyé tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí bẹ̀rẹ̀ àtúnyẹwò iṣẹ́ ìdá Kejì nínú ọdún ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìlànà tí a ti ṣètò nípasẹ̀ 'Central Delivery Coordinating Unit' CDCU ní ilé-iṣẹ́ Ààrẹ. ‎ ‎ Nígbàtí o n sọrọ ní àpéjọ…

Ìjọba Nàìjíríà Ṣé Ìdádúró Àwọn Àjọṣepọ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Lókè Òkun Fún Ọdún Márún

Mínísítà fún ètò Ẹ̀kọ́, Dókítà Maruf Alausa, tí kéde ìdádúró ọdún márún lórí àjọṣepọ̀ ètò ẹ̀kọ́ lókè òkun látí ṣé ìdàgbàsókè àlàáfíà fún àwọn ọmọ Ilé-ìwé. ‎ ‎ Nígbàtí o n sọrọ lẹ́yìn àtúnyẹwò nlá tí àwọn ètò ẹ̀kọ́ ní àwọn ìlú òkèèrè,…

Ààrẹ Bola Tinubu tí kí Ààrẹ Ẹgbẹ́ Dangote, Alhaji Aliko Dangote, lórí yíyàn rẹ̀ sí ilé-iṣẹ́ ìdókòwò…

Ààrẹ Bola Tinubu tí kí Ààrẹ Ẹgbẹ́ Dangote, Alhaji Aliko Dangote, lórí yíyàn rẹ̀ sí ilé-iṣẹ́ ìdókòwò aládàáni ti banki àgbáyé. ‎ ‎ Ilé-iṣẹ́ Ìdókòwò Aládàáni tí Bánkì Àgbáyé jẹ́ 'apá kán tó níí ṣé pẹ̀lú ìgbéga ìdókòwò àti ṣiṣẹda iṣẹ́ ní…

Ijoba Ebonyi Ṣé Ìdásílẹ̀ Àgbègbè Fún Àwọn Ilé-iṣẹ́ Túntún ‎

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi Francis Nwifuru tí bẹ̀rẹ̀ kíkọ àgbègbè ilé-iṣẹ́ kan ní ìpínlẹ̀ náà, Gúúsù ìlà òòrùn Nàìjíríà. ‎ ‎ Àgbègbè ilé-iṣẹ́ náà, èyítí o wà lẹgbẹẹ ilé-iṣẹ́ iṣelọpọ paipu tí ìpínlẹ̀ náà, yóò bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn òpópó-ònà tó…
button