Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà AbdulRazaq Rọ Àwọn Aráàlú Láti Ṣ’àtìlẹ́yìn Fún-un Bí Ọdún 2026 Ṣé Bẹ̀rẹ̀

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara, Àárín Gbùngbùn Àríwá Nàìjíríà, AbdulRahman AbdulRazaq, ti ké sí àwọn aráàlú láti dúró ṣinṣin nínú àtìlẹ́yìn wọn fún ìṣàkóso rẹ̀ bí ọdún 2026 ṣé bẹ̀rẹ̀. ‎ ‎Ó ṣèlérí pé ìjọba yóò tẹ̀síwájú nínú ìsapá rẹ̀ láti mú…

Ìtọ́nisọ́nà Ṣé Pàtàkì Sí Ìgboyà Láti Darí Gẹ́gẹ́bí Aṣáájú Dáadáa – Mínísítà

Mínísítà fún Ìròyìn àti Ìtọ́sọ́nà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Idris, ti tẹnu mọ́ ìmọ̀ràn àti ìtọ́sọ́nà gẹ́gẹ́ bí òun pàtàkì sí ìgboyà fún ẹnikẹ́ni láti darí bí aṣáájú réré. ‎ Mínísítà fún Ìròyìn sọ ọ̀rọ̀ yìí níbi ìpàdé kan tí…

Àṣeyọrí Àtúnṣe Ètò-ọrọ Àjé Ní Kí Ilé-iṣẹ́ NNPCL Gúnlè Fún Ìtẹ̀síwájú – Ààrẹ Nàìjíríà

Ààrẹ Bola Tinubu tí gbá àwọn ìgbìmọ̀ túntún fún ilé-ìfọpo Nàìjíríà (Nigerian National Petroleum Company Limited NNPCL) tó ṣé ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ gúnlè ìlọsíwájú tó ṣé nípasẹ àwọn àtúnṣe ètò-ọrọ àjé, èyítí o fí gbóríyìn fún Imúdára àti ìpèsè ayé…

Ó Lé Ní Ẹgbẹ̀rún Mẹ́talá Àwọn Oníjágìdíjagán Tí Á Tí Dá Lọ́wọ́ Kọ́ Láàrín Oṣù Kàrún 2023 Sí Ọdún Yìí…

Olùdámọ̀ràn Ààbò tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NSA), Mallam Nuhu Ribadu, tí sàlàyé pé ó lé díẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́talá àbọ̀ (13,543) àwọn oníjágìdíjagán àti àwọn afurasi ọdaràn mìíràn ní a tí dá lọwọ́ kọ́ yọ́ kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti oṣù…

Ààrẹ Tinubu Ṣàfihàn Ìlọsíwájú Ẹgbẹ́ APC Sí Àwọn Àtúnṣe Ètò Ọrọ-àjé ‎

Ààrẹ Bola Tinubu tí sọ pé àtìlẹ́yìn tó ń pọ̀ sí i fún ẹgbẹ́ òṣèlú 'All Progressives Congress' (APC) ló jẹ́ àṣeyọrí àgbàyanu tí ẹgbẹ́ náà ṣe láàárín ọdún méjì àkọ́kọ́ tí wọ́n ti lò lẹ́nu iṣẹ́ ìjọba, ó sì fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé…

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kéde Ìbẹ̀rẹ̀ Àjọ̀dún Eré Ìdárayá Orílẹ̀-èdè

Tí ìdùnnú tí ayọ̀ ní gbogbo àwọn ènìyàn wà nílùú Abeokuta, tó jẹ́ olu-ilu ìpínlẹ̀ Ogun, nígbà tí Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe kéde ayẹyẹ eré ìdárayá ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún ní ìforígbárí, pẹ̀lú àwọn olóyè, àwọn olóṣèlú, àwọn ògbóǹtagí eré ìdárayá…
button