Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ibùdó Ìtajà Fáàárí Ńlá Ni Borno L’ójúnà Látí Pèsè Iṣẹ́ ‎

Ìjọba Nàìjíríà tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ọjà fáàárí nlá kán ni Maiduguri, Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Borno, pẹ̀lú afojusun látí pèsè iṣẹ́ tó fẹ́ tó ẹgbẹ̀rún àádọ́ta nípasẹ ilé-iṣẹ́ náà. ‎ ‎ Ní ìtẹ̀síwájú àtìlẹ́yìn tí oní bílíọ̀nù márùn-dín-lọgọ́rin (N75b)…

Ní Ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹta, Nàìjíríà Ṣèlérí Láti Mú Ìrọ̀rùn Bá Ọnà Látí Gbá Ìwé Ìrìnàjò Ní Kíkún

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí kéde ọjọ́ kínní Oṣù kẹta ọdún yìí gẹ́gẹ́ bí ìbẹrẹ ọjọ́ tí ìwé ìrìnnà yóò dí tí orí ayélujára pátápátá l'ójúnà látí mú ìrọ̀rùn àti ààbò bá àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ‎ ‎ Mínísítà fún intiriọ, Dókítà…

Ìbúgbàmù Ọkọ̀ Àjàgbé èpò: Ààrẹ Tinubu Darí Àjọ NOA Láti Bẹ̀rẹ Ìpolongo Kàn Jákèjádò Orílẹ̀-èdè

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti pàṣẹ fún àjọ tó ń ri sí ìpolongo (National Orientation Agency NOA), láti bẹ̀rẹ̀ ìpolongo ètò ẹ̀kọ́ jákèjádò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún àwọn aráàlú lórí ewú tó wà nínú gbígba èpò tó dànù nígbàtí àwọn ọkọ̀ àjàgbé èpò…

Ìyàwó Ààrẹ Tí Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ilé-ìwé Gíga Túntún Fún Àwọn Ọmọ Obínrin Ni Ìpínlè Osun

Ìyáàfín àkọkọ́ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ìyáàfín Oluremi Tinubu, tí ṣí ilé-ìwé túntún fún àwọn ọmọbìnrin tó jáde kúrò ní ilé-ìwé nítorí oyún àìlérò, ìwa-ipá nínú ilé àti àwọn ìṣòro owó láti máṣe juwọ́ sílẹ̀ láti ṣaṣeyọri àwọn àlá àti…

Matawalle Gbóríyìn Fún Ààrẹ Tinubu Fún Sísán-wó Ẹ̀tọ́ Àwọn Ológun ‎

Mínísítà fún ètò ààbò, Dókítà Bello Muhammed Matawalle, tí dúpẹ́ fún Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu, fún ìgbésẹ tó ṣé pàtàkì látí ríi dájú pé sisán owó oṣù àwọn ológun ní kíákíá pẹ̀lú ajẹ́-sílẹ oṣù mẹ́ta. ‎ ‎ O tún dúpẹ́ lọ́wọ́ Ààrẹ fún owó àwọn…

Olórí Ilé-iṣẹ́ Ológun Gbèrò Láti Máa Ṣiṣẹ́ Pọ̀ Pẹ̀lú Áwọn Oníròyìn ‎

Olórí Òṣìṣẹ́ Ilé-iṣẹ́ ogún (COAS), Lt. General Olufemi Oluyede, tí pé fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin àwọn Ológun àti àwọn Oníròyìn láti kojú àwọn italaya ààbò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ‎ ‎ Oluyede tún gbá àwọn Oníròyìn Gúúsù Ìlà-oòrùn ní ìmọràn…

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Tí Nàìjíríà Tí Kọ́ Àhesọ Ọrọ̀ Lórí Àtúnṣe Owó-orí ‎

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Nàìjíríà tí kọ́ àwọn ìròyìn tí àwọn àkọròyìn kán kọ́ pé àwọn tí yẹ́ba kúrò lórí ìjíròrò àwọn Àtúnṣe Òfin Owó-orí. ‎ ‎ Nígbàtí Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà náà, Godswill Apabio ń s'ọrọ ní ìpàdé wọ́n ní Ọjọ́bọ̀, Ó…

‎Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ Bẹ́nu Atẹ Lú Awuyewuye Tó Ń Lọ́ Lórí Gúúsù Ìwọ̀-oòrùn Sí Ilé-iṣẹ́ Ààbò ‎

Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ tí bẹ́nu àtẹ lú ìròyìn kán pé ìṣàkóso Ìjọba Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ń kọjú sí Gúúsù Ìwọ̀-oòrùn pẹ̀lú ni ìpinnu láti yàn Olórí ààbò rẹ̀ nibẹ̀. ‎ ‎ Ní ìdáhùn si àwọn àtakò náà, Ọ̀gbẹ́ni Sunday Dare, Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Ààrẹ…
button