Take a fresh look at your lifestyle.

Ọmọ Ogún Orílẹ̀ Nàìjíríà Yóò Tẹ̀síwájú Láti Máà Fún Àwùjọ Padà – Olórí Ọmọ Ogún

Olórí ẹgbẹ́ ọmọ Ogún (COAS) Lieutenant General Faruk Yahaya sọ pé ọmọ Ogún Nàìjíríà lábẹ́ iṣọ rẹ̀ yóò tẹsiwaju láti fún àwùjọ padà nípa ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àti àtìlẹ́yìn tó nípa ti awọn ara ilu n ṣé láti mú òfin ìlú dúró. Nínú àtẹ̀jade…

Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà Fẹ́ Ètò tó Dára Fún Bọ́ọ̀lù Afẹsẹgba Ní ilẹ̀ Nàìjíríà

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà (ANFPU), tí pepe fún ṣíṣe ètò àti ìlànà tó dára jùlọ fún gbogbo ìpele tí bọ́ọ̀lù afẹsẹgba nti orílẹ-èdè náà. Abdul Sule, Alàkóso tí ẹgbẹ́ náà sọ pé, liigi agbabuta gbogbo orílẹ-èdè ní o má n ṣé ìdàgbàsókè…
button