Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò 2023, Ààrẹ Buhari Ń Wàásù Ìpolongo Tó Dà Lórí Ọ̀nà Àbáyọ́

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ṣé itẹwọgbà ipilẹsẹ tí Ìgbìmọ̀ Àlàáfíà tí Orílẹ̀-èdè yìí ṣé bí wọ́n fí ọwọ́ gbogbo awọn olóṣèlú Olùdijé ipò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà bí ìpolongo ìbó kò ṣé gbọdọ da lori inúnibíni, ẹgàn arà ẹní àti ikọlù. Nínú…
button