Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ rọ ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra láti gba àwọn Abarapá tó bá kúnjún òsuǹwọ̀n níṣẹ́

Àkójọpọ̀ Ẹgbẹ́ àwọn Abarapá lórílẹ̀-èdè (JONAPWD), ẹ̀ka ìpínlẹ̀ Anambra, ti rọ Gómìnà Chukwuma Soludo láti fún àwọn Abarapá tó bá kúnjún òsùnwọ̀n ní iṣẹ́ nínú ìgbanisíṣẹ́ olùkọ́ni tí ń lọ lọ́wọ́ báyìí ní…

Àwọn Abarapá ṣàjọyọ̀ àyájọ́ káríayé ní ìpínlẹ̀ Kaduna

Bí gbogbo àgbáyé ṣe ṣayẹyẹ àyájọ́ àwọn Abarapá ní ọjọ́ kẹta, oṣù kejìlá, 2023, ni ẹnì kọ̀ọ̀kan tí ó jẹ́ abarapa ní Nàìjíríà ń pè fún kí àwọn náà wà lára olùkópa nínú àwọn ètò ọmọnìyàn. Ẹgbẹ Akojọpọ…

NECO kil̀ọ̀ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti ṣọ́ra fún ìwà burúkú nínú ìdánwò

Alákóso, tí ó tún jẹ́ Aláṣẹ Àgbà fún ìgbìmọ̀ tó ń mójútó ìdánwò ilé-ìwé gíga aláṣekágbá lórílẹ̀-èdè, NECO, Ọ̀jọ̀gbọ́n Dantani Ibrahim Wushishi ti rọ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ń kọ ìdánwò alábájáde (SSCE) 2023,…

Ilé iṣẹ́ tó ń mójútó ọ̀rọ̀ ibùgbé, yóò ṣàjọṣepọ̀ pẹ̀lú ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àwọn òṣìṣẹ́,…

Ilé iṣẹ́ ìjọba tó ń mójútó ọ̀rọ̀ ibùgbé àti ìdàgbàsókè ìlú ti ṣetán láti jọṣepọ̀ pẹ̀lú ilé ẹ̀kọ́ gíga ti ibùdó àwọn adári fún ìṣàkóso ilé iṣẹ́ láti pèsè ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti Ìrónílágbára fún àwọn…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara kò ní fààyè gba ítọrọ lórí títì

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara, Àríwá Àringbùngbùn Nàìjíríà, nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan rẹ̀ láti jẹ́ kí àwọn ìwà ìbàjẹ́ kúrò nílẹ̀, ti ṣàpèjúwe títọrọ àti bí àwọn alárùn ọpọlọ ṣe ń rìn káàkiri lórí títì bí…
button