Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí Jonathan kí àwọn ọmọ lẹ́yìn Kírísítì kú ọdún Kérésìmesì
Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí Goodluck Ebele Jonathan ti kí gbogbo ọmọ Nàìjíríà kú ọdún Kérésìmesì, tí ó sì ń rọ̀ wọ́n láti ní ìfẹ́, àlààfíà, ìrẹ̀lẹ̀ ọkàn, àti ìfìgbádùn ara ẹni sílẹ̀ fún nǹkan mìíràn.
Ninu…