Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò ilé gbígbé lórílẹ̀-èdè: Ilé iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ ṣàtúnyẹ̀wò ilé títà

Ilé iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó ń mójútó Iṣẹ́ àti Ilé gbígbé ní Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ ètò láti ṣàtúnyẹ̀wò ilé títà lábẹ́ Àgbékalẹ̀ Ilé gbígbé lórílẹ̀-èdè. O sọ eleyi ninu alaye kan ti o si si ori X  rẹ.…

Anambra: Ìyàwó Gómìnà pín àwọn ohun jíjẹ fún àwọn àlùfáà ní ibùgbè wọn

Ìyàwó Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ìyáàfin Nonye Soludo, ti ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ohun jíjẹ fún àwọn Àlùfáà Kátólííkì tí wọ́n ń gbé ní ibùdó àlàáfíà ní Awka, olú ìlú náà. Iyaafin Soludo sọ pe abẹwo naa…

Kò ní sí àfikún owó PMS – ilé-iṣẹ́ NNPC fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú

Ilé-iṣẹ́ tí ń mójútó ètò epo ilẹ̀ ní Nàìjíríà lápapọ̀, (NNPC) ti fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé kò sí èròńgbà àti fi owó kún owó Premium Motor Spirit (PMS), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Pẹtirólù…

Wọ́n búra fún ọmọ Somalia-Amẹrika alákọ̀ọ́kọ́ tí wọ́n dìbò yàn ní Amẹ́ríkà

Ìgbìmọ̀ ìlú ti St. Louis Park ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, ní Minnesota ti búra fún Nadia Mohamed, tíí ṣe ọmọ ọdún mẹ́tàdín-lọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí mayor, oṣù méjì lẹ́yìn tí ó ṣẹlẹ̀ nínú ìtàn tí àwọn olùdìbò yàn ọmọ…

Ààrẹ Tinubu kí Gómìnà Uba Sani kú oríire ní ọdún mẹ́tàlé-láàdọ́ta

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú Gómìnà Uba Sani ti ìpínlẹ̀ Kaduna fún ọjọ́ ìbí ọdún mẹ́tàlé-láàdọ́ta rẹ̀, tí ó sí gbóríyìn fún ìfisọ́kàn tiwantiwa àti ìṣọ̀kan orílẹ̀-èdè. Wọn bi ni ọjọ…
button