Take a fresh look at your lifestyle.

Kòsí iṣẹ́ Àkànṣe kankan tí yóò dúró lójú ààrẹ Tinubu – Mínísítà

Mínísítà Nàìjíríà fún olu ́ ìlú (FCT), Ọ̀gbẹ́ni Nyesom Wike, ti fi ìdùnnú rẹ̀ hàn lórí pé kòsí iṣẹ́ Àkànṣe kankan tí ìṣàkóso FCT bẹ̀rẹ̀ tí wọ́n dá dúró lábẹ́ ìṣàkóso ààrẹ Bọla Tinubu. Minisita ti o sọ…

Ìgbìmọ̀ ní ó tó gẹ́, ilé yá fún àwọn ọmọ Nàìjíríà

Ìgbìmọ̀ tó ń mójútó àwọn tí wọ́n sálọ sí ilẹ̀ míràn fún ààbò, arìnrìn àjò àti àwọn tí wọ́n fipá ṣí nípò lórílẹ̀-èdè, ti sọ pé òun ti ṣetán láti kó àwọn tí wọ́n sálọ sí ilẹ̀ míràn fún ààbò tí…

Adarí Nàìjíríà pè fún àjọṣepọ̀ tó túnbọ̀ dánmọ́rán pẹ̀lú Faransé lórí ìgbógunti…

Ààrẹ Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu, ti pè fún àjọṣepọ̀ tó túnbọ̀ dánmọ́rán pẹ̀lú Faransé, tí ó sì sọ pé àtúnṣe lórí ìfọwọ́sowọ́pọ̀ iṣẹ́ ọnà láàrin Nàìjíríà àti Faransè yóò ṣẹ́gun jàgídíjàgan àti…

Gómìnà Ọyọ gba Adarí ilé iṣé tí ń pèsè ààbò fún ará ìlú lálejò, pinnu àtìlẹyìn

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ, Ṣeyi Makinde, ti gba Adarí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tí ń pèsè ààbò fún Naijiria àti ará ìlú (NSCDC) tuntun, ti ikọ̀ ìpínlẹ̀ Ọyọ, Commandant Augustine Padonu, lálejò ní ọ́fíísì Gómìnà ní Ibadan, olú…

Ilé iṣẹ́ ṣe àbẹ̀wò sí ẹbí àwọn afaragbà ìjàm̀bá ọkọ̀ ojú omi ní ìpínlẹ̀ Anambra

Ilé iṣẹ́ tí ń mójútó ìṣàkóso pàjáwìrì lórílẹ̀-èdè, NEMA, ilé iṣé ìpínlẹ̀ tí ń mójútó ìṣàkóso pàjáwìrì, SEMA, àti iwọ̀ oòrùn ìjọba ìbílẹ̀ Anambra , ti ṣèdárò pẹ̀lú ẹbí Ọ̀gbẹ́ni Sunday Nnalue,…
button