Owó ìrìn àjò Hajj 2024: Àwọn olùrìnrìn àjò yóò san iye owó tó tó mílíọ́nù márùn…
Ìgbìmọ̀ tó ń mójútó ìrìnrìn àjò Hajj ní Nàìjíríà (NAHCON), ti sọ pé iye owó tó tó mílíọ́nù márùn ún Náírà ni àwọn tó fẹ́ rin ìrìn àjò lọ sí ilẹ̀ mímọ́ láti Nàìjíríà yóò san.
Iye owo naa yatọ…