Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun buwọ́lu gbígba ẹgbàárún olùkọ́ni síṣẹ́
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun iwọ̀ oòrùn Nàìjíríà ti buwọ́lu gbígba ẹgbàárún olùkọ́ni àti àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìwé ọ̀tà-dín-lẹ́ẹ́wá-lé-nígba sí ṣẹ́.
Gẹgẹ bi iroyin ti wọn fi sita ti Olawale Rasheed, ti agbẹnusọ fun gomina…