Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ tó ń pèsè ètò ìnáwó fún ilé-ẹ̀kọ́ gíga TETFund ṣàgbékalẹ̀ owó fún Àwọn ilé…

Àjọ tó ń pèsè ètò ìnáwó fún àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga, TETFund, sọ pé òhun yóò ṣàtìleyìn fún ìṣèwádìí tí ó gbòòrò  sí àwọn ilé -iṣẹ́ gbogbogboò mẹ́rin,tí Ilé -iṣẹ́ Orílẹ̀ -èdè fún ìṣèwádí àti…

Ààrùn covid ti di ẹgbàáta- lé- ní- ọ̀kẹ́- mẹ̀wáá- ó- lé- ní- èjì- dín -–lọ́gọ́je ní…

Ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NCDC ) ṣọ pé,ààrùn ọ̀hún ń pọ̀ si ni lójoojúmọ́,ènìyàn mẹ́rìnlé-láàdọ́rin miràn ló tún ti kó ààrùn náà ní ọjọ́ àìkú. Ajọ naa sọ…

Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ṣe ìfìlọ́lẹ̀ pápá ìdaráyá ìkẹ́kọ̀ọ́ jákè jádò Nàìjíríà

Ẹgbẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà sọ pé, ọ̀gá àgbà fún àwọn  Ológun (COAS), ajagun Faruk Yahaya yóò ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìdárayá GOLDEN DAWN,ENDURING PEACE àti STILL WATER jákèjádò orílẹ̀-èdè ní ọjọ́ àìkú,ọjọ́ kẹrin,oṣù…

Nàìjíríà kí orílẹ̀- èdè China kú oríire ayẹyẹ ọdún kejì –lé- làádọ́rin

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti fi ìdùnnú rẹ̀ hàn  sí Ààrẹ Xi Jinping, fún ìrántí àseyẹ ọdún kejì – lé – láàdọ́rin  Orílẹ̀ -èdè  China, èyí tí ó wáyé ní ọjọ́ kínní, Oṣù Kẹwàá, Ọdún 2021. Aarẹ   yin fun…

Ìdáàbòbò Àwọn amáyédẹrùn Pàtàkì ṣe pàtàkì fún Ààbò lórí ìmọ̀ ayélujára…

Mínísítà fún ètò Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ọrọ̀ Ajé orí ayélujára , Ọ̀jọ̀gbọ́n Isa Pantami sọ pé, àyàfi tí wọ́n  bá gbé àwọn ìgbésẹ̀ àdáṣe láti dáábòbò àwọn amáyédẹrùn pàtàkì àti àwọn ohun -ìní…

Ìgbìmọ̀ àwọn mínísítà Nàìjíríà buwọ́lù iye owó tó tó bílíọ́nù méjì Náírà…

Ìgbìmọ̀ Aláse ìjọba àpapọ̀ ti fọwọ́sí iye owó tó tó bílíọ́nù méjì Náírà  fún àwọn àdéhùn márùn ún ní Ilé -ẹkọ́ gíga fáfítì Nnamdi Azikiwe, Awka, Ìpínlẹ̀ Anambra. Ibuwọlu naa waye  nibi ipade minisita ni…

Covid-19: Àwọn ènìyàn mèje -dín- ní -okòó-lé-ní-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta míràn tún ti ní ààrùn…

Ní ọjọ́ kọkànlé-lógún oṣù kẹsàn án,ọdún 2021, ènìyàn mẹ́tàlá –lé –lẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta míràn ló tún ti kó ààrùn covid, tí ènìyàn mẹ́ta sì jọ́lọ́run nípè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,gẹ́gẹ́ bíi ilé iṣẹ́ tó ń…

Igbákejì ààrẹ Òsínbàjò ń darí àpèjọ pẹ̀lú ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀

Igbákejì ààrẹ Yẹmí Ọ̀ṣínbàjò ń darí àpèjọ pẹ̀lú ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ lórí ayélujára ní ilé-ìlú . Osinbajo n ṣe alaga ipade naa nitori pe  aarẹ Muhammadu Buhari  wa ni New York, Orilẹ- ede Amẹrika, lati kopa ninu…
button