Ìjọba Àpapọ̀ Tún Ti Sún Gbèdéke Ìforúkọsílẹ̀ NIN àti SIM Síwájú
Ìjọba àpapọ̀ ti sún gbèdéke fún ìforúkọsílẹ̀ NIN àti SIM síwájú. Èyí tí ó yẹ kí ó wá sí òpin ní ìparí oṣùn kẹẁáa; sùgbọ́n ìgbìyànjú láti ríi pé gbogbo ènìyàn ní àǹfààní láti kópa nínú…