Take a fresh look at your lifestyle.

NCC ṣèfilọ́lẹ̀ Òṣùwọ̀n Ìfòpìnsí Káríayé Alágbèéká Tuntun

Ìgbìmọ̀ Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NCC) ti ṣe àgbékalẹ̀ Òṣùwọ̀n Ìfòpinpín Káríayé tuntun (ITR) fún áwọn iṣẹ́ ohùn tí ó ń san nípasẹ̀ àwọn oníṣẹ́ ẹ̀rọ ìbánisòrò  òkèèrè fún dídí…

 Ìforúkọsílẹ  nọ́mbà Ìdánimọ̀ Nàìjíríà fẹnusọ àádọ́rin mílíọ́nù  – NIMC

Ìgbìmọ̀ Ìṣàkóso nọ́mbà Ìdánimọ̀  Orílẹ̀-èdè NIMC ti ṣàlàyé pé ó ti làlùyọ tó lámì  nípa ṣíṣe gbígba orúkọsílẹ̀ àti fífún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn olùgbé tótó àádọ́rin…

 Ìgbìmọ̀  ṣe ìfilọ́lẹ̀ ibùdó tuntun fún àwọn asásálà   ní ìpínlẹ̀ Nasarawa

Ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ  láti pèsè ààbò àti ìrànlọ́wọ́ fún ènìyàn nípa pípèsé ìtùnú fún àwọn  tí  àjálù kàn, Ìgbìmọ̀  Orílẹ̀-èdè fún Àwọn Asásálà, Àwọn tì wọ́n ṣí láti ibìkan sí…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Faransé gbìmọ̀ láti ṣàgbéga ojú ọjọ́ lárugẹ

Ìjọba Nàìjírià àti Ilé-iṣẹ́ tó ń risi Ìdàgbàsókè Faransé, AFD ti tún ṣe ìpinnu láti teramó ìfowósowópò wọn láti ṣe ìgbéláruge iṣé ojú-ọjọ́ àti ìdàgbàsókè ètò- ọrọ̀-ajé  orílẹ̀-èdè.…

orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣí ìpàtẹ ọjà elẹ́ẹ̀kẹrin fún àwọn okòòwò abẹ́lé

Nàìjŕíà ti ṣíí ìpàtẹ ọjà ẹlẹ́ẹ̀kẹrin fún àwọn olókòòwò alábọ́ọ́dé ,MSMEs, ní Ìpínlẹ̀ Imo. Ṣiṣii ohun elo ti a pin, eyiti o jẹ aaye nibiti ijọba pese ọpọlọpọ awọn ohun elo ati awọn ẹrọ fun oniruuru karakata…

Ilé ìgbìmọ̀ aṣojú yóò ṣewádìí ìkọlù tó ṣẹlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Pilatú

Ilé ìgbìmọ̀ aṣojú ti ṣàgbékalẹ̀ ìgbìmọ̀ elénìyàn mẹ́jọ kan láti  ṣèwádìí bí pípànìyàn ṣe ń pọ̀si ní ìpínlẹ̀ Pilatú ṣe lájọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn adigunjalè,pàápàjùlọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Wase àti àwọn agbègbè…

Àwọn Gómìnà Àríwá-Ilà-oòrùn gbèrò Ètò ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn oníjàgídíjàgan tí…

Ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà Àríwá-Ilà-oòrùn ti pari àpèjọ ìpele ẹlẹ́ẹ̀kẹfà rẹ̀ ní Dámátúrú,ní ìpínlẹ̀ Yóbè,tí wọ́n sì rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba Nàìjìríà láti ṣàgbékalẹ̀  Ètò ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn…
button