Take a fresh look at your lifestyle.

Ìbò abẹ́lé APC Edo: APC ní kò rí bẹ́ẹ̀ o, ẹni tí kò láṣẹ láti kéde ìbò kò le kéde rẹ̀…

Ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress, APC, ti sọ pé irọ́ ni ò, ẹni tí kò láṣẹ láti kéde ìbò abẹ́lẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Edo, Gúsù Nàìjíríà tí ń lọ lọ́wọ́, kò kéde o. Akọwe ipolongo lapapọ ti ẹgbẹ oṣelu All…

Ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ fún Áfíríkà yóò bẹ̀rẹ̀ ní 2028

Ààrẹ Nàìjíríà Bọla Ahmed Tinubu ti sọ pé ìjọba òun yóò jẹ́ kí ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ́ Àdúláwọ̀ ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè ẹgbẹ́ láti ri pé Ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ fún Adúláwọ̀ bẹ̀rẹ̀ ní 2028, bí wọ́n ti ṣètò…

Àwọn ìyàwó Agbófinró ṣe ìrónilágbára fún àwọn obìnrin ní ìpínlẹ̀ Anambra

Ẹgbẹ́ àwọn ìyàwó Agbófinró (POWA), ti ṣe ìrónilágbára fún àwọn obìnrin márùnlé-láàdọ́rin nípa kíkọ́ wọn ní orísirísi iṣẹ́ ọwọ́ àti àwọn ohun èlò láti fi bẹ̀rẹ̀ isé náà ní ìpínlẹ̀ Anambra. Nigba ti o n fa…

Àwọn olùṣàkóso ilé ẹ̀kọ́ gíga Fáfítì Ibadan ṣèpàdé pẹ̀lú àwọn aṣojú akẹ́kọ̀ọ́

Àwọn olùṣàkóso ilé ẹ̀kọ́ gíga Fáfítì Ibadan (UI), Ibadan, ní ìpínlẹ̀ Ọyọ, ti ṣe ìpàdé pẹ̀lú àwọn aṣojú akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé náà. Adari ile iwe ọhun (VC), Ọjọgbọn Kayọde Adebọwale, mni, FAS, ṣalaye pe ipade naa, leyi…

Wọ́n ti gbajúgbajà ilé ìtajà Abuja kan pa fún ẹ̀sùn àìsedéédé owó ọjà

Ìgbìmọ̀ tó ń mójútó ètò ìdáàbòbò ìdíje àti àwọn olùrajà lápapọ̀ (FCCPC), ti ti gbajúgbajà ilé ìtajà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Sahad Stores Limited, lórí ẹ̀sùn ìyànjẹ, àti àṣìlọ́nà owó ìtajà. Wọ́n…
button