Take a fresh look at your lifestyle.

Óókàn- lé- lọ́ọ̀dúnrún àwọn ọmọ Nàìjíríà míràn tún ti fi orílẹ̀-èdè Ukirénì…

Gẹ́ǵẹ bí ìjọba Nàìjíríà ṣe ń kó àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè rẹ̀ kúrò ní Ukiréénì, àwọn óókàn-lé-lọ́ọ̀dúnrún míràn àti ọmọ ìkókó kan tún ti dé sí pápá òfurufú Nnamdi Azikwe ní ìlú Àbújá,Olú-ìlú.…

Àwọn aṣojú tí ó ní ìwé-àṣẹ nìkan ni yóò le ra ọjà tààrà láti ọ̀dọ̀ àwọn àgbẹ̀…

Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ (FEC) ti fọwọ́sí pé àwọn aṣójú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nìkan tí ó ní ìwé-àṣẹ ni yóò le ra ọjà tààrà láti ọ̀dọ̀ àwọn àgbẹ̀ àti títà fún àwọn àjèjì. Ifọwọsi yii waye nibi ipade  …

Igbákejì ààrẹ Òsínbàjò ń darí àpèjọ pẹ̀lú ìgbìmọ̀ aláṣẹ lórí ayélujára

Igbákejì Ààre orílè-èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò  ń dari  ìpàdé  Ìgbìmọ̀ aláṣẹ lórí ayélujára, èyítí ó bẹ̀rẹ̀ ní agógo mẹ́wàá òwúrọ̀ ní òwúrọ̀ Ọjọ́bọ̀. Igbakeji aarẹ ni alaga ipade naa…

Gómìnà Ganduje ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn òṣìṣẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàje -ó -lé- ní- èjì- dín- lọ́rin…

Gẹ́gẹ́ bí àpéjọpọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) ti ń súnmọ́ sí, èyí tí ó mú kí Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje ti ìpínlẹ̀ Kano  ṣe ìfilọ́lẹ̀ gbogbo àwọn òṣìṣẹ́  ẹgbẹ́ tí wọ́n yàn jákèjádò ìjọba…

COAS rọ àwọn ọmọ ogun láti mú ìpinnu wọn sẹ lórí iṣẹ́ wọn

Ọ̀gá àgbà fún àwọn Òṣìṣẹ́ Ilé-ogun (COAS),ajagun Faruk Yahaya ti rọ àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà láti dúró ṣinṣin lórí ìpinnu wọn àti dídojúkọ àṣẹ òfin iṣẹ́ tí wọ́n gbà èyí tí ó jẹ́ ìdáábòbò ẹ̀tọ́ agbègbè…

Abba Kyari Sọ fún adájọ́ pé òhun ò jẹ̀bi ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án

Igbákejì Kọmísánnà ọlọ́pàá tí wọ́n dádúró, DCP, Abba Kyari, ti ṣàlàyé níwájú Adájọ́ Emeka Nwite, ti ilé-ẹjọ́ gíga ti Àbújá,olú ìlú Nàìjíríà lórí àwọn ẹ̀sùn gbígbé òògùn olóró tí ilé-iṣẹ́ tó ń…
button