Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé Pè Fún Àwọn Àtunṣe Ìgbékalè Láti yọ Àwọn ọmọ Nàìjíríà…

Ẹgbẹ́ ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé sọ  pé ìgbékalẹ̀ àtúnṣe tí ó jinlẹ̀ ṣe pàtàkì ní kíákíá  láti yọ àwọn mílíọ̀nù  ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kúrò nínú ìpọ́njú,ó kìlọ̀ pé  ìdá mẹ́tàdín-lógún  àwọn…

2023: Olùdíje Ààrẹ lábẹ́ àsìá PDP, Ṣe ìlérí láti kojú Àwọn ìtaláyà Nàìjíríà

Olùdíje Ààrẹ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ Peoples Democratic Party (PDP), Dókítà Nwachukwu Anakwenze,ti ṣe ìlérí láti ṣàtúnṣe ètò-ọrọ̀ ajé  orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,gbógun ti  ìwà ìbàjẹ́ àti ìdàgbàsókè ètò ààbò…

Ilé-iṣẹ́ Ìlera Kọ̀ ìdásílè Àwọn ilé-ìwé Tuntun

Àwọn tí ó ṣe pàtàkì ní ẹ̀ka ìlera ti kọ̀jálẹ̀ pé láá,kò sí dídásílẹ̀ ilé-èkọ́ ìlera míràn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí gẹ́gẹ́ bí Ìgbésẹ̀ tí Ilé-ìgbìmọ aṣòfin agbà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe tí yóò de  …

Nàìjíríà Ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ìlànà ètò Lórí Àwọn tí wọ́n fipá ṣínípò padà, IDPs

Ìjọba Nàìjíríà ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ìlànà ètò lórí Àwọn ènìyàn tí wọ́n fipá ṣínípò padà , IDP, ní orílẹ̀-èdè. Minisita fun eto ọmọniyan, Iṣakoso Ajalu ati Idagbasoke Awujọ, Sadiya Umar Farouq ṣe ifilọlẹ lilo eto  …

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Pọ́túgàlì ṣàbẹ̀wò sí ilé Iṣẹ́ Ìkẹ́kọ̀ọ́ EU Ní Mòzámbíkì

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Pọ́túgálì, Marcelo Rebelo de Sousa, parí ìrìn-àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ta rẹ̀ sí Mòsáḿbíkì pẹ̀lú àbẹ̀wò sí àwọn ikọ̀ méjì ilé- iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ àjọ aláwọ̀ funfun, EU ní orílẹ̀-èdè náà. Lakoko ibẹwo…

Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Tùnísíà fi ẹ̀hónú hàn ní ìlòdì sí Ààrẹ Saied

Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ọmọ orílè-èdè Tùnísíà péjọ ní olú-ìlú ní ọjọ́ àìkú,tí ó jẹ́ ọjọ́ òmìnira orílẹ̀-èdè ọ̀hun, láti fi ẹ̀hónú wọn hàn ní ìlòdì sí Ààrẹ Kais Saied àti ìjíròrò lórí àwọn àtúnṣe…

Orílẹ̀-èdè Níú sìlaǹdì yóò Pès̀e Ukiréínì Pẹ̀lú Ìrànlọ́wọ́ ológun tí kìí ṣe…

Orílẹ̀-èdè Níú sìlaǹdì sọ ní ọjọ́ àìkú pé òhun yóò pèsè orílẹ̀-èdè Ukiréínì pẹ̀lú iye owó NZ $ mílíọ̀nù márùn ún ($ 3.46 million) àti ìrànlọ́wọ́ ológun tí kìí ṣe apànìyàn pẹ̀lú díẹ̀ nínú ohun…
button