Take a fresh look at your lifestyle.

COAS gbóríyìn fún Àwọn ọmọ ogun Fún àìtúrásílẹ̀ àti ìfaradà wọn

Ọ̀gá àgbà  fún àwọn ọmọ ogun, ajagun Faruk Yahaya (COAS), sọ pé òhun  nírètí  pẹ̀lú àìtúrasílẹ̀ àti ìgboyà  àwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè (NACA)  àti ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó ìdánilékọ̀ọ́ àwọn ologun,  (NATRAC)…

Ìjàǹbá Ìjì ilẹ̀: Nàìjíríà bá orílẹ̀-èdè Amẹ́ríká kẹ́dùn

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti bá  orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà  àti àwọn ènìyàn rẹ kẹ́dùn  lori ìjì ilẹ̀  tí ó jà káàkiri ní ìpínlẹ̀ mẹ́fà,ní eléyìí tí ó ba ọ̀pọ̀lọpọ̀ dúkìá jẹ́  tí ó sì tún mú ẹ̀mí dání. O sọ pe ohun ba gbogbo awọn…

Alákóso ilé-ẹ̀kọ́ gíga OAU gbèrò ẹ̀kúnwó Fún Àwon ilé-ẹ̀kọ́ gíga Nàìjíríà

Alákóso Fáfítì Ọbáfémi Awólọ́wọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n Èyítọ́pé Ògúnbọ́dẹdé ti képè fún ẹ̀kúnwó ìṣàkóso  àwon ilé ìwé gíga Nàìjíríà. Ọ̀jọ̀gbọ́n Ogunbọdẹde pe ìpè náà ní Èkó, lákòókò ti wọn n ṣàgbékalẹ̀   the Great…

Igbákejì ààrẹ Òsínbàjò yóò fọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀ níbi àpèjọ ìgbìmọ̀ àgbáyé ilé…

Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọ̀sínbàjò ní ọjọ́bọ̀ yóò fọ̀rọ̀ jomitoro ọrọ níbi àpèjọ àgbáyé ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó afẹ́fẹ́ gáásì ní Dubai, United Arab Emirates. Oluranlowo pataki  fun  aarẹ lori…

FEC: Ḿinísítà fún Àwọn ọ̀dọ́ yóò Ṣàgbékalẹ̀ Àtẹ̀jáde NYSC kan lórí Owó Ìrànlọ́wọ́

Mínísítà fún Àwọn ọ̀dọ̀ àti Ìdàgbàsókè Eré-ìdárayá ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sunday Dare, ti ṣe ìlérí láti ṣàgbékalẹ̀ ìwé-ákọọ́lẹ̀   fún ìdásílẹ̀ owó ìrànlọ́wọ́ fún àgùnbánirọ̀  (NYSC) fún  …

Ọwọ́ pálábá àwọn ọ̀daràn sẹ́gi, ẹ wòó bi ikọ̀ ọmọ ogun Nàìjíríà ṣe sewọ́n bí ọsẹ se ń…

Ṣe ọj,ọ́ kan ni tolè ọjọ́ kan ni tolohun, Ikọ ọmọ ogun orilẹ ede Naijiria pẹlu ikọ̀ ọmọ  òfúrufú ati awọn agbofinro to wa ni ,ilà oòrùn àríwá (NE), Operation HADIN KAI (OPHK) ti daná sun ọ̀pọ̀lọpọ̀ ikọ  ọlọtẹ Boko Haram (BH) àti…
button