Mínísítà rọ àwọn tó fẹ́ gba ìwé ìrìnnà láti máá gba ọ̀nà ẹ̀bùrú
Ìjọba Àpapọ̀ ti kìlọ̀ fún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ń bèèrè fún ìwé ìrìnnà káríayé láti yàgò fún àwọn onímọ̀dàrú àti àwọn tí wọ́n ṣe àpèjúwe wọn gẹ́gẹ́ bí àwọn òṣìṣẹ́ aláìlóòtọ́,…