Kòsí aáwọ̀ kankan láàrin àwọn aláṣẹ àti aṣòfin – ilé-iṣẹ́ ààrẹ
Ilé-iṣẹ́ ààrẹ ti sojú abẹ níkòó lórí àríyànjiyàn tí ó wáyé láàrin Aláṣẹ àti àwọn abala aṣòfin ìjọba lórí àwọn àtúnṣe inú ìsúná ọdún 2022.
Agbẹnusọ fun Aarẹ, Garba Shehu, ninu ọrọ kan, sọ pe awuyewuye…