Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ ojúṣe rẹ̀ gẹ́gẹ́ Bí Akọ̀wé D- 8 Gbogbogboọò Ní Tọ́kì

Asojú Nàìjíríà sí orílẹ̀-èdè Tọ́kì, Ísíákà Abdulqadir Imam ti gba iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Akọ̀wé Àgbà ti D-8 àjọ ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ọrọ̀-ajé  ní Istanbul, Tọ́kì. Gẹ́gẹ́ bí àtẹ̀jáde Abdullahi Tukur ti ilé iṣẹ́ ìjọba ilẹ̀ òkèèrè…

A ó kéde àwọn adigunjalè gẹ́gẹ́ bíi oníjàgídíjàgan láìpẹ́ – AGF

Ọ̀gá àgbà fún ètò ìdájọ́ (AGF) àti Mínísítà fún Ìdájọ́, Abubakar Malamí, sọ pé ìkéde àṣẹ ilé-ẹjọ́ tí yóò kéde  àwọn adigunjalè gẹ́gẹ́ bí oníjàgídíjàgan yóò bọ́síi láìpẹ́. O sọ asọye naa lakoko ti o…

Ààbò oúnjẹ-Àwọn ọlọ́ṣà pa ọgọ́ta àgbẹ̀ alágbàdo ní Katsina

Garba Lawal Alaga MAAN, ìpínlẹ̀ Katsina,sọ pé, Àìtó àgbàdo lọ́dún 2022 ti di èyí tí kò ṣeé yẹ̀ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ alágbàdo ní Nàìjíríà, (MAAN) pàdánù nǹkan bí ọgọ́ta ọmọ ẹgbẹ́ wọn nínú ìkọlù àwọn ọlọ́ṣà , tí àwọn àgbẹ̀ kan si sá lọ sí…

Àwọn àlejò sí Ilé olú-ìlú yóò máa ṣe àyẹ̀wò ààrùn còrónà

Ààrẹ sọ pé láti ìsìsìyí lọ, àwọn àlejò sí Ilé- ìlú yóò ní láti ṣe àyẹ̀wò ààr̀un còrónà  ní iyàrá  ẹnu-ọ̀nà, ṣaájú kí wọ́n tó le wọlé sí gbàgede náà . Oluranlọwọ pataki  fun aarẹ lori eto iroyin ati…
button