Take a fresh look at your lifestyle.

Adarí Nàìjíríà ṣàtẹ́wọ́gbà àdéhùn ikọ̀ ọlọ́kanọ̀jọ̀kan pẹ̀lú Qatar

Ààrẹ Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti fi dá ìjọba Qatari lójú pé òun ti ṣetán láti ṣàtẹ́wọ́gbà àwọn ìdókòwò sí orílẹ̀-èdè, ó ní òun mọ ìpeniníjà tí orílẹ̀-èdè ń kojú lọ́wọ́ ṣùgbọ́n pé ìjọba òun ń ṣe…

Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger kí àwọn aláṣẹ ìgbìmọ̀ olùkọ̀wé ìròyìn NUJ tuntun kú oríire

Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger, Alhaji Mohammed Umaru Bago, ti ki Mustapha Yakubu Bina kú oríire fún títúnyàn bíí alága àwọn olùkọ̀wé nínú ìwé ìròyìn ti ẹgbẹ́ àwọn oníròyìn ní Nàìjíríà (NUJ), ẹ̀ka ìpínlẹ̀ Niger.…

Igbákejì ààrẹ Shettima ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ tó ń mójútó ìrìn àjò mímọ́ tuntun

Igbákejì ààrẹ Kashim Shettima ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ tó ń mójútó ìrìn àjò mímọ́ tuntun ní Naijiria NAHCON, tí ó sì ń rọ̀ àwọn olùṣàkóso tuntun náà láti mú ìṣe tuntun wọ iṣẹ́ ìrìn àjò lọ sí ilẹ̀…

Kò sí ẹni tí yóò pàdánù iṣẹ́ rẹ̀ nínú àtúnṣe tí ìjọba ń ṣe—Mínísítà

Mínísítà Nàìjíríà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ìṣàlàyé, Mohammed Idris, ti sọ pé ìjábọ̀ Oronsaye, léyìí tí ó gbà àdọ́gbọ́nsí àwọn ilé iṣẹ́ ìjọba, kò ní jásí ìpàdánù iṣẹ́ tàbí kó pa àwọn iṣé…

Àwọn Adúláwọ̀ tí wón ń gbé lórílẹ̀-èdè mííràn, ṣe pàtàkì fún ìdàgbàsókè –…

Ìgbìmọ̀ tí ń mójútó ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà tí ń gbé lórílẹ̀-èdè mííràn, (NIDCOM), ti sọ pé kí Áfíríkà tó gbèrú lórí ìbáraẹniṣepọ̀ ọrọ̀ ajé, ìlọsíwájú àti ìdàgbàsókè, kọ́kọ́rọ́ rẹ̀ wà pẹ̀lú…

Arábìnrin àkọ́kọ́ Anambra rọ àwọn obìnrin tó ń tọ́mọ lọ́wọ́ láti ṣe àfikún omi ọyàn tí…

Ìyàwó gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ìyáàfin Nonye Soludo ti rọ àwọn obìnrin Nàìjíríà tó ń tọ́mọ lọ́wọ́ ni Anambra, láti ṣe àfikún omi ọyàn tí wọ́n ń fún àwọn ọmọ wọn ki omi máá baà le gbẹ lára wọn, nítorí bí ooru…
button