ASUU fi oṣù méjì kún ìyanṣẹ́lódì rẹ̀
Àjọ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ olùkọ́ni ilé-ẹ̀kọ́ gíga fáfítì tún ti sún ìyanṣélódì rẹ̀ síwájú pẹ̀lú oṣù méjì.
Ìgbìmọ̀ aláṣẹ ẹgbẹ́ ọ̀hún lápapọ̀,NEC ló gbé Ìgbésẹ̀ láti tẹ̀síwájú lórí ìdaṣẹ́sílẹ̀ náà níbi…