NMA ṣèdárò lórí ikú arábìnrin Dókítà tí ó pàdánù ẹ̀mí ẹ̀ nínú ìkọlù ọkọ̀ ojú…
Ààrẹ Ẹgbẹ́ Ìṣègùn Nàìjíríà (NMA), Ọ̀jọ̀gbọ́n Innocent Ujah, sọ pé gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ ìṣègùn àti ehín lábẹ́ àbójútó NMA ni ó banújẹ́ lórí iṣẹlẹ aburú, tí ó tún bani lẹ̀rù tí ó fa ikú Dókítà Chinelo Nwando, ẹni tí wọ́n pa nínú ìkọlù…