Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí rọ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ APC láti ṣera wọn lóṣùṣù ọwọ̀

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti rọ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) láti wà ní ìṣọ̀kan, kí wọ́n sì yẹra fún ìwàkiwà, kíkó àwọn aṣojú jọ ní àpéjọpọ̀ àkànṣe náà láti ronú dìbò yan ààrẹ tó ní àǹfààní púpọ̀ jù lọ láti jáwé…

A ní láti ro ọjọ́ ọ̀la àwọn ọmọ wa ká tó dìbò yàn- Ọ̀ṣínbàjò

Igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò sọ ní kùtùkùtù òwúrọ̀ Ọjọ́ọ́rú pé, ríro ọjọ́ iwájú àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè yìí ṣe pàtàkì fún àwọn asojú sí Àpèjọ Abẹ́lé Ààrẹ All…

Gómìnà kéde ìṣọfọ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Òndó Fún Àwọn olùfaragbà

Gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó ní Gúúsù-Iwọ̀ oòrùn Nàìjíríà, Olúwarótìmí Akérédolú ti pàsẹ fún gbogbo ilé, ohun èlò àti ibùgbé òṣìṣẹ́ láti ta àsìá Nàìjíríà ní ìdajì fún ọjọ́ méje ní ìyẹ́sí  àwọn tó…
button