Hajj 2022:Àwọn arìnrìn- àjò lọ sílẹ̀ mímọ́ nípínlẹ̀ Kàdúná yóò gbéra
Wọ́n ti rọ àwọn arìnrìn-àjò lọ sílẹ̀ mímọ́ láti ìpínlẹ̀ Kàdúná pé kí wọ́n tẹ̀ lé ìlànà ẹ̀sìn mùsùlùmí nígbà tí wọ́n bá ń rìnrìn àjò náà.
Alaṣẹ akọwe,ajọ ti o n ṣe amojuto awọn eniyan to n rinrin-ajo lọ silẹ mimọ nipinlẹ Kaduna,…