Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ìgbìmọ̀ Lórí síso Àwọn ilé-iṣẹ́ Ìjọba pọ̀

Ilé-̀ìgbìmọ̀ Aṣojú lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣe ìfílọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ pàjáwìrì kan láti ṣe ìwádìí Ìṣẹ́pọ̀ àwọn iṣẹ́  ilé-iṣẹ́  ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olori ile igbimọ aṣoju, Hon. Fẹmi…

Ìpínlẹ̀ Niger ṣe ìfilọ́lẹ̀ ètò Ẹ̀kọ́ orí ayélujára Fún Àwọn ọ̀dọ́ àti Àwọn ọmọdé

Ìjọba ìpínlẹ̀ Niger ní  Àáríwá  Nàìjíríà, ti ṣe ìgbékalẹ̀ ètò kan láti ṣètìlẹ́yìn fún kíkọ́ àwọn ọmọdé àti àwọn ọ̀dọ́. Wọ́n ṣe ìfilọ́lẹ̀ pẹpẹ ètò yìí ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú  Àjọṣepọ̀ Ẹ̀kọ́ Àgbáyé (GPE) àti àjọ ìṣọ̀kan tí ń rí…

Igbákejì ààrẹ Ọ̀ṣínbàjò ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀

Ìpàdé ọlọ́sẹ̀ẹ̀sẹ̀ Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ ní gbọ̀ngàn ìgbìmọ̀, ní Víllà, Àbújá, pẹ̀lú Igbákejì Ààrẹ Yẹmí Ọ̀ṣínbàjò. Ọjọgbọn Ọṣinbajo lo n dari ipade naa nigba ti Aarẹ Muhammadu Buhari ti lọ si orilẹ-ede…

A yóò ṣa gbogbo ipá wa láti ran Sẹ́nétọ̀ tó wà nínú làásìgbò lọ́wọ́

Olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣojú-ṣòfin Nàìjíríà, Aṣojú Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà sọ pé òun ti pá láṣẹ fún Ìgbìmọ̀ aṣojú Nàìjíríà ní UK, láti fún Sẹ́nétọ̀ Ike Ekweremadu, ní gbogbo ìrànlọ́wọ́ tí ó nílò lórí…
button