Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí kí igbákejì rẹ̀, Ọ̀ṣínbàjò kó dárayá kíákíá

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti kí Igbákejì rẹ̀ 'Yẹmí Ọ̀ṣínbàjò kí ó dárayá pátápátá ní  kíákíá, lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ tí ó ṣe ní ọjọ́ Àbámẹ́ta láti ṣe ìtọ́jú ìrora tí ó ń jẹ nípasẹ̀  ẹsẹ̀ rẹ̀ tí ó kán.…

Àwọn ọmọ Nàìjíríà ṣojú Ní WAFCON 2022, Ìpele Ẹgbẹ́ XI tí ó dára jùlọ

CAF ti fi orúkọ àwọn olùdíje mọ́kànlá (XI) tí ó dára jùlọ ti ìdíje Àwọn obìnrin agbábọ́ọ́lù Áfíríkà ọdún 2022 síta, lẹ́yìn ìparí ìpele ìdíje ẹgbẹ́  náà pẹ̀lú àwọn agbábọ́ọ́lù Nàìjíríà méjì, Rasheedat…

Aarẹ Nàìjíríà rọ àwọn olùkọ́ yunifásítì láti fòpin sí ìyanṣẹ́lódì

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhari ti késí Ẹgbẹ́ oṣìṣẹ́ olùkọ́ni  fáfítì, ASUU, pé kí wọ́n yí ìpinnu wọn padà lórí ìdasẹ́sílẹ̀ ọlọ́jọ́ pípẹ́ tí wọ́n rawọ́ lé,ó bàá nínú jẹ́ pé ìyanṣẹ́lódí náà yóò ní àbájáde ìrandíran lórí àwọn…
button