Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari yóò lọ síbi ìpàdé àwọn adari ajọ ilẹ Afirika ní Rwanda

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí yóò kúrò  ní ìlú Àbújá lónìí,Ọjọ́ọ́rú, ọjọ́ kejìlé-lógún sí Kìgálì,lórílè-èdè Rwanda, láti kópa nínú ìpàdé àwọn adarí àjọ ilẹ̀ Adúláwọ̀ ẹlẹ́ẹ́kẹrìndín-lọ́gbọ̀n (CHOGM),…

Hajj 2022: Ìpínlẹ̀ Kàdúná pàdánù arìnrìn àjò lọ sílẹ̀ mímọ́ méjì

Àwọn arìnrìn àjò méjì láti ìjọba ìbílẹ̀ Igabi ní ìpínlẹ̀ Kàdúná, Àriwá Nàìjíríà, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Yakubu Abdulsamad àti Haruna Suleiman ti jẹ́pè ọlọ́run. Wọn jẹpe oluwa ni ọjọ Abamẹta ati Ọjọ Ajẹ lẹsẹẹsẹ ki…
button