Take a fresh look at your lifestyle.

Olórí Orilẹ Èdè, Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti kéde ikú Ọga àgbà ọmọ ogun Orilẹ Èdè Nàìjíríà ẹni tó di…

Olórí Orilẹ Èdè, Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti kéde ikú Ọga àgbà ọmọ ogun Orilẹ Èdè Nàìjíríà, Taoreed Abiodun Lagbaja, ẹni tó di oloogbe ni ẹni ọdún Merindinlọgọta (56). Lagbaja, ẹni tí wọn bí ní ọjọ́ Kejidinlọgbọn oṣù Kejì, Ọdún 1968…

Ọjọ́ Oúnjẹ Lágbàáyé: Makinde Ṣèlérí Ìpèsè Oúnjẹ Lọpọ Yanturu Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí pé ìṣèjọba òun kò ní tẹti nínú ìpèsè oúnjẹ ní Ìpínlẹ̀ náà. Makinde, ẹni tó sọ di mímọ̀ pé, ìjọba ti gbe onírúurú ìgbésẹ̀ láti mú kí iṣẹ́ àgbẹ̀ gbèrú síi lójúnà àti mú kí oúnjẹ pọ̀ yanturu,…

Orilẹ Èdè Nàìjíríà Ní Agbára Láti Gòkè Àgbà: Òjíṣẹ Ọlọrun Owoseni

Alákòóso àti Olùdásílẹ̀ Iṣẹ́ Ìhìnrere African Jerusalem, Òjíṣẹ́ Ọlọrun Gideon Owoseni ti gba ọmọ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà níyànjú láti ní ìgbàgbọ́ pé ọjọ́ ọ̀la Orílẹ̀ èdè yìí yóò dára Òjíṣẹ́ Ọlọrun Owoseni, ẹni tó sọ di mímọ̀ pé Orílẹ̀ Èdè…

Ẹ Na Ọwọ́jà Iṣẹ́ Yin Sí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ – Makinde Sì Ilé Iṣẹ́ Ológun Ojú Òfurufú Orílẹ̀ Èdè…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti sọ di mímọ̀ pé ìṣèjọba rẹ̀ fẹ́ ki Ilé iṣẹ́ ológun ojú òfurufú (Air Force) na ọwọ́jà iṣẹ́ rẹ̀ láti la ipa rere ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Makinde fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé, ìṣèjọba òun yóò tẹ síwájú láti máa ṣé…

Àṣà Àti Ìrìn-Àjò Afẹ́: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ṣèlérí Láti Gbárùkù Ti Ẹ̀ka Ìrìn-Àjò Afẹ́

Ní ojúnà àti mú kí ọrọ̀ ajé rú gọ́gọ́ síi, Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti ṣèlérí láti gbárùkù ti ẹka ìrìn-àjò afẹ́ Ìpínlẹ̀ náà. Komisana fún Àṣà àti Ìrìn Àjò Afẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ọ̀mọ̀wé Wasiu Olatunbosun lo sọ èyí di mímọ̀ lásìkò ìjíròrò…

Oyè Jíjẹ Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́: Makinde Ṣèlérí Láti Mú Àtúnṣe Débá Ìgbìmọ̀ Lọ́ba Lọ́ba

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí pé ìṣèjọba òun ti ṣetán láti mú àtúnṣe dé bá ìgbìmọ̀ àwọn l'ọba l'ọba àti oyè jijẹ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, nígbà tó fi kún pé àsìkò ti tó fún èyí. Makinde ló sọ ọ̀rọ̀ yìí lásìkò tó ṣe ìpàdé pẹ̀lú…

Makinde Fi Ẹ̀bùn Ọkọ̀ Méjìdínlọ́gbọ̀n (28) Fún Àwon Ọmọ Ilé Ẹ̀kọ́ Gíga.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí wí pé, bo tilẹ̀ jẹ́ pé ohun gbogbo gbé owó lórí, ìṣèjọba òun yóò tẹ̀ síwájú láti máa ṣe ohun tí yóò mú kí ará tu àwọn ènìyàn Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Gómìnà lo sọ ọ̀rọ̀ yìí lásìkò tó n fi ọkọ̀ elérò…
button