Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Tẹ́lẹ̀ rí, Ọmọlolu Olunlọyọ Jáde Láyé
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti fi ikú ẹni tó ti fi ìgbà kan rí jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ọ̀mọ̀wé Victor Ọmọlolu Olunlọyọ wé àdánù nlá
Makinde lo sọ ọ̀rọ̀ yìí nínù àtẹ̀jáde kan eléyìí to fi kẹ́dùn pẹ̀lú ìdílé Olunlọyọ, gbogbo ọmọ…