Àṣìta Ìbọn: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kẹ́dùn Pẹ̀lú Ìdílé Ọ̀dọ́mọdé-kùnrin Kan Tó Pàdánù Ẹ̀mí Rẹ̀
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lábẹ́ ìṣàkóso Gómìnà Seyi Makinde ti bá ìdílé ọ̀dọ́mọdé-kùnrin kan to pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ látàrí àṣìta ìbọn.
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí fi aidunnu rẹ̀ hàn sí ìṣẹ̀lẹ̀ àṣìta ìbọn náà eléyìí tó gba ẹ̀mí ọmọkùnrin kan to nlọ ṣe…