Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia Ṣe Ìkìlọ Fún Àwọn Ènìyàn Ìpínlẹ̀ Náà Nípa Ìtọ́jú Ojú Tí Kò Tọ̀nà.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia Alex Otti ti pé àkíyèsí àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Abia latari bi wọn ṣe n se ìtọjú ojú wọn ní ọna ti ko tana. Gómìnà ni èyìn leè ṣe òkùnfà kí ojú náà fò pátápátá Lai sí àtúnṣe. Ó ṣe ìkìlọ náà ni ọjọ́rú lásìkò ìfilọ́lẹ̀…
button