Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Gbé Òsùbà O káre Fún Oníròyìn Àgbà Bisi Olatilo Fún Àádọta Ọdún Lẹnu Iṣé Ìròyìn.

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu ti gbé Òsùbà o káre fún Aláṣẹ àti Olùdarí ilé iṣé Biscom Communication, Ọmọba Bisi Olatilo fún ayẹyẹ àádọta ọdún lénu iṣé ìròyìn. Ààrẹ gbóríyìn fún ọmọba Olatilo fún akitiyan, ipá mọra, ìfẹ àti…

Ayẹyẹ ayajọ IDEOF: Irin Yóò Wáyé Ni Ìlú Abuja Àti Kaduna Láti Sààmì Sí Ayajọ Ọdún Náà.

Ẹgbẹ́ tí wọn pẹ ni (BFFWH) ti sọ wí pé ayẹyẹ ayajọ ọdún yii yóò dá lórí ìrìn láàrin Ìlú Abuja àti Kaduna. Ibukun Ogundara tó jẹ agbẹnusọ fún ẹgbẹ́ náà ni o sọ èyí di mímọ̀ lásìkò to n ba àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ ni Kaduna, o ni kókó ìrin náà…

Ìpínlẹ̀ kano Buwọ́lù Lu Biliọnu Mẹta Fún Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Ti Yóò Ko Ìdánwò.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti ya owó Biliọnu Mẹta sọ tọ́ láti ṣe iranlọwọ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti yóò ko ìdánwò NECO ni ọdún yìí. Ó ní èyí wa ni ìbámu pẹ̀lú èròngbà ìjọba ìpínlẹ̀ náà láti ṣe àtìlẹ́yìn fún ètò ẹ̀kọ́ àti ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn.…

Mínísítà Fún Okò Ofurufu Ṣe Ìbẹ̀wọ̀ Si Orílè-èdè Brazil Láti Mú ìdàgbàsókè Ba Ètò Okò Ofurufu…

Lára èròngbà Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu láti mú ìdàgbàsókè àti irẹpọ ba Orílè-èdè Nàìjíríà àti South American, Mínísítà fún ètò ọ̀rọ̀ okò òfurufú Festus Keyamo ti ṣe Orílè-èdè Brazil fún ìmọ to péye lori iṣé náà. Mínísítà…

Gẹ́gẹ́ Bí Òbí Ẹ Rí Dájú Wí Pé Ẹ kópa Nínu Ètò Ẹ̀kọ̀ Àwọn Ọmọ Yìí: Ọgá Agba Fásítì.

Oga àgbà Fásítì Tansian ni Umunya, ni ìjọba ìbílẹ̀ Oyi ni ìpínlẹ̀ Anambra, ọmowé Eugene Nwadialor ti sàlàyé pàtàkì ti o wá nínú ki obi kópa nínu ètò ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ wọn. Ó ní yóò mú ìdàgbàsókè àti àṣeyọrí nlá bá ọmọ náà, nitori obí a tètè…
button