Ààrẹ Muhammadu Buhari ti yan àwọn alákoso titun fún àtuhntò ọrọ̀ ajé. Ó sọ pé, pèlú àìrajaja tí ó ń bá ètò ọrọ̀ ajé f́inra ní àgbáyé, ọrọ̀ ajé Nàìjíríà sì ń gbèrú síi.
Nígbal tí ó ń fi ètò náà lọ́lẹ̀, ààre sàlàyé pé, àrùn Covid-19, Ogun orílẹ̀ èdè Ukraine àti sísòfò Epo rọ̀bì fa ọrọ̀ ajé nàìjíríà séyìn.
Ààre Buhari ni ó jẹ́ alága àjo náà, nígbà tí igbákejì ààre ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Òsíbajò, dókítà Kayọde Fayemi àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ sì jẹ́ ara àjọ náà.
Leave a Reply